Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ NEMA Ti Mú Àwọn Ọmọ Nàìjíríà Tí Ìrìn Àjò Wọn Sí Ìlu ́Libya Ti Forí Sọ́npọ́n…

Aj̀ọ tó ń rí sí ètò pàjáwìrì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (NEMA), ní ọjọ́ ọjọ́rú ti gba àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà marundinlọgọrun (95) tí ìrìn àjò wọn sí ìlú Libya ti forí sópón padà wá sí ìlú…

Ilé-ìgbìmọ̀ aláṣẹ Nàìjíríà buwọ́lu ìdásílẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ gíga fáfítì sáyẹ́ǹsìì…

Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ àpapọ̀ ti fọwọ́sí dídásílè ilé-ẹ̀kọ́ gíga àpapọ̀ fáfítì ti sáyẹ́ńsìì ìlera  ní Otukpo, Ìpínlẹ̀ Benue. Wọn buwọluu ni  Ọjọbọ, nibi ipade  Igbimọ Alase apapọ ti Aarẹ Muhammadu Buhari ṣe adari rẹ.…

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin buwọ́lù ẹ̀yáwọ́ látòkèèrè Fún Àwọn amáyédẹrùn Pàtàkì

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin  lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti fọwọ́sí ìbéèrè  ẹ̀yáwó  bílíọ̀nù mẹ́rìndínlógún dọ́là àti bílíọ̀nù kan Euro lábẹ́ ètò ẹ̀yáwó ìjọba látókèèrè  ti ìjọba 2018-2021. Ifọwọsi naa wa…
button