Take a fresh look at your lifestyle.

‎’Rivers United’ Àti ‘Power Dynamos’ Tí Ṣetán Láti Kojú Ara Wọn Nínú Ìdíje ‘CAF Champions League’ ‎

59

Rivers United tí ṣetán fún ifẹsẹwọnsẹ pàtàkì tí ọjọ́ Àbámẹ́ta yìí, bí wọn yóò ṣé kojú ikọ̀ ‘Power Dynamos FC’ tí Zambia nínú ìdíje tí ‘CAF Champions League’.

‎Ikọ̀ Rivers United tí gbéra lọ sí Ndola ni Zambia pẹ̀lú ìgboyà láti borí àwọn akẹ́gbẹ́ wọn nínú ìdíje náà fún ìgbà àkọ́kọ́ ní sáà yìí.

Comments are closed.

button