Balógun Super Eagles ti Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, William Troost-Ekong, tí buwọ́lù ìwé àdéhùn pẹ̀lú sí ẹgbẹ́ Qatar kán Al Ahli SC.

Troost-Ekong, ọmọ ọdún méjìlèlọ́gbọ̀n 32, agbábọ́ọ̀lù ẹyin kúrò nínú ẹgbẹ́ Saudi Al Kholood — níbi tó ti ń ṣé déédéé tó sì ti ṣojú fún ní ìgbà mọ́kàndínlàádọta 49, tó sì gba àmì ayò méjì wọlé. Ó tí fọwọ́ sí àdéhùn pẹ̀lú Al Ahli tí yóò wà títí di oṣù kẹfà ọdún 2028.
Comments are closed.