Take a fresh look at your lifestyle.

Ìfètò Sí Ọmọbíbí: Àjọ Tí Ọ̀rọ̀ Kàn Àti Ìjọba Ìpínlẹ̀ Sokoto Jẹ́jẹ̀ẹ́ Ìrànlọ́wọ́ Fún Ará Ìlú

0 148

Àjọ Àgbáyé tí ó siṣẹ́ lórí òǹkà ọmọnìyàn àti Ijọba Ìpínlẹ Sokoto ti sàlàyé ìlànà àti ètò ìrànlọ́wọ́ owó fún fífi ètò sí ọmọ bíbí

 

Igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Sokoto, Alhaji Idris Gobir, ẹni tí ó se agbátẹrù ètò náà sàlàyé pàtàkì àti ìlànà fún ìfètò sí ọmọbíbí

 

Gobir, ẹni ti Kọmísọ́nà Fún Ètò Ìjọba Ìbílẹ̀ ní Ìpínlẹ Sokoto, Alhaji Ibrahim Dade-Adare sojú fún sé àfirinlẹ̀ ìgbáradì ìjọba ìpínlẹ Sokoto láti tán ìsòro tí ó ń kojú ìlànà ìlera.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button