Take a fresh look at your lifestyle.

Látàrí Rúkè-rúdò Tí Ó Ń Sẹlẹ̀ Ní Orílẹ̀-èdè Uganda, Àjọ Àgbáyé Sèkìlọ̀ Fún Àwọn Ará Ìlú

0 280

Orílẹ̀-èdè United States Àti United Kingdom ti sèkìlọ̀ fún àwọn ènìyàn wọn tí ó ń gbé Orílẹ̀-èdè Uganda láti jìnà sí kíkópa níbi ayẹyẹ tàbí ètò ìjọsìn fún ààbò ẹ̀mí wọn.

 

Ìkìlọ̀ náà wáyé síwájú ọdún Nyege Nyege èyí tí ìrètí wà pé yóò wáyé ní àyájọ́ Ọjọ́bọ̀

 

Bẹ́ẹ̀ ní ìkìlọ̀ tún wá pé kí wọ́n jìnà sí ilé ijó àti àwọn àyè ìta gbangba míràn fún ààbò ẹ̀mí wọn.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button