Take a fresh look at your lifestyle.

CAF Ṣé Àyípadà Ọjọ́ Ìfẹ́sẹwọ́nsẹ̀ Enyimba Àtí Wydad Sí Ọjọ́ kẹ́rindìnlọgbọ́n Oṣù Kẹwàá

0 302

Àjọ àgbábọ́ọ̀lù ilẹ̀ Áfíríkà tí sùn ifẹsẹwọnsẹ Kéjì láàrin Wydad Casablanca tí Morocco àti Enyimba FC tí Ilẹ̀ Nàìjíríà nínú ìdíje bọ́ọ̀lù Áfíríkà tí ń lọ lọ́wọ́ látí ọjọ́ kẹẹdọgbọn sí ọjọ́ kẹrindinlọgbọn oṣù kẹwàá.

Èyí ló wáyé lẹyìn ẹsùn pé àwọn aláṣẹ Ìlú Morocco ń gbé àwọn ìgbésẹ̀ tó burú láti bá inú àwọn àgbábọ́ọ̀lù Enyimba jẹ́ – èyí tó fá kí ẹgbẹ́ náà fí ẹsùn kàn wọ́n.

David Orji, Alàkóso ibanisọrọ tí ẹgbẹ́ Aba, sọ èyí nínú ọrọ kàn ní ìlú Èkó

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button