Take a fresh look at your lifestyle.

A Kìí Fi Ọlá Jẹ Iyọ̀: Ẹ Mú Àdíkù Bá Iyọ̀ Ní Jíjẹ Láti Dènà Àrùn- Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra Pàrọwà

0 252

Aya Gómìnà Ìpínlẹ̀ Anambra, Arábìnrin Nonye Soludo ti pè fún àmójútó tí o péye nípa ìpèsè àwọn ohun jíjẹ ní àwùjọ fún ìlera ọmọnìyàn.

 

Arábìnrin Soludo sọ ọ̀rọ̀ náà ní ìlu Awka níbi àgbéyẹ̀wò ètò ìlera nípa àtẹ̀jáde àjọ elétò ìlera àgbáyé tí ó sàfihàn wipe àjẹjù iyọ̀ nínú ońjẹ ni o n fa ikú eniyan ti ko dín ní ẹgbẹ̀rún méjì láàrin ọdún kan.

 

Ó wá pàwọwà sí àwọn ara ilu lati jina si ounjẹ ti o ba ni àpọ̀jù iyọ tabi súgà ninu lati dena àrùn ti o le è se ikú pani ní rèwe-rèwe.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button