Take a fresh look at your lifestyle.

Àyájọ́ Olùkọ́: Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe Yóò Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ẹ̀kọ́

0 178

Gómìnà Muhammadu Inuwa ti ìpínlẹ̀ Gombe ti se ìfiléde ìpinnu rẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ẹ̀kọ́ àti ìgbáyégbádùn àwọn olúkọ́.

 

Ó tún gbèrò láti pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn láti mú ìrọ̀rùn bá iṣẹ́ síṣe ní ẹka ètò ẹ̀kọ́

 

Gómìnà sọ ọ̀rọ̀ náà níbi àyájọ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí ó wáyé jákè-jádò gbogbo àgbáyé.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button