Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ọmọ Ogún Turkey Márùn Pàdánù Ẹ̀mí Wọ́n Ní Iraq

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 379

Àwọn ọmọ-ogun Turkey márùn ní wọ́n pá nínú ikọlù kàn pẹ̀lú àwọn onijagidijagan tí Ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ Kurdish (PKK) tí wọ́n fí òfin dè ní àríwá Iraq.

Ilé-iṣẹ́ ààbò ti Turkey sọ pé rògbòdìyàn náà wáyé ní àgbègbè Zap, níbití Turkey tí n ṣé iṣẹ́ ààlà kàn tí a pé ní “Claw-Lock.”

Ankara sọ pé èyí jẹ́ ìwọn láti ṣé ìdìwọ́ fún PKK kó má lè ní anfààní látí ló Iraq gẹ́gẹ́ bí ìpìlẹ̀ látí gbé iná wò ojú Turkey.

PKK, tó ní àwọn ibùdó ní àyíká àríwá Iraq, ní Turkey, Amẹ́ríkà, àtí Àjọ Yúrópù tí pé ní ẹgbẹ́ apanilaya. Ẹgbẹ́ náà ṣé ìfilọ́lẹ̀ iṣọtẹ kàn ní gúúsù ìlà-oòrùn Turkey ní ọdún 1984 èyítí o pá ènìyàn tó jú ogójì ẹgbẹ̀rún lọ́.

Gẹ́gẹ́ bí ìṣẹ́ àkànṣe náà ṣé ńlọ́, èyítí wọ́n ṣé ìfilọ́lẹ̀ rẹ̀ ní Oṣù Kẹrin ọdún 2022 títí dì òní, àwọn ẹgbẹ̀ta dín díẹ̀ Onijagidijagan 586 ní ọwọ́ tí bá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button