Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpàdé Ẹgbẹ́ ECOWAS Tí Nlọ́ Lọwọ́

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 260

Ìpàdé tí ẹgbẹ́ àwọn Olórí Orílẹ̀-èdè tí Ìwọ̀-oòrùn Áfíríkà ECOWAS, tí fẹ́ bẹ̀rẹ báyìí ní Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ, Abuja, Olú-ìlú Nàìjíríà.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Tinubu, tó jẹ́ Alága ẹgbẹ́ náà ní yóò dárí ìpàdé náà.

Alága ECOWAS, Bola Tinubu, pé ìpàdé náà ní Ọjọ́ Ajé, látí ṣé àkíyèsí àwọn ìgbésẹ láti dá ìjọba tiwa-n-tiwa pàdà ní Orílẹ̀-èdè Niger.

Ìfipágbàjọba ló ṣẹ̀lẹ̀ ní Orílẹ̀-èdè Niger ní Ọjọ́rú, ọjọ́ kẹrindinlọgbọn, Oṣù Keje, lọwọ́ Ààrẹ Mohammed Bazoum. Ṣùgbọ́n ẹgbẹ́ náà gbé ìgbésẹ akin bí wọ́n ṣé ṣé àwọn ijẹniniya kàn fún Orílẹ̀-èdè náà tí wọ́n sì fún wọ́n ní ọjọ́ méje èyí tó parí ní ọjọ́ Àìkú, ọjọ́ kẹfà oṣù kẹjọ.

Gbogbo Àgbáyé ní báyìí ń dúró dé àwọn àbájáde ìpàdé òní, pẹ̀lú ìrètí àyípadà réré.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button