Take a fresh look at your lifestyle.

CAF Champions League: Power Dynamos Àti Rivers United Tá Ọmi

73

Ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ fún Rivers United láti ní àmì mẹ́ta lórí tábìlì nínú idije CAF Champions League láàrín ikọ náà ati power Dynamos, ni papa iṣere Levy Mwanawasa ní Ndola, Zambia lo wá sí òfo.

‎ Rivers United ati Power Dynamos bẹrẹ pẹlu ìwúrí ní ìdá àkọ́kọ́ nínú ìdíje náà ṣùgbọ́n abajade ifẹsẹwọnsẹ náà yọrí sí omi, bí ẹgbẹ́ méjèèjì ṣe wà ní ìsàlẹ̀ tábìlì àkọ́kọ́ (Group A).



‎ Àbájáde ọjọ́ Àbámẹ́ta nínú ìdíje CAF Champions League

‎Power Dynamos 0-0 Rivers United

‎RS Berkane 0-0 Pyramids

‎Kabylie 0-0 AS FAR

‎Esperance 1-0 Simba.


Comments are closed.

button