Rivers United tí ṣetán fún ifẹsẹwọnsẹ pàtàkì tí ọjọ́ Àbámẹ́ta yìí, bí wọn yóò ṣé kojú ikọ̀ ‘Power Dynamos FC’ tí Zambia nínú ìdíje tí ‘CAF Champions League’.

Ikọ̀ Rivers United tí gbéra lọ sí Ndola ni Zambia pẹ̀lú ìgboyà láti borí àwọn akẹ́gbẹ́ wọn nínú ìdíje náà fún ìgbà àkọ́kọ́ ní sáà yìí.
Comments are closed.