Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ-èdè Nàìjíría Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Ìgbìmọ̀ ìmọ̀isẹ́ Àgbáyé Láti Ṣe Àlẹ́kún ìdúróṣinṣin Lágbayé 

16

Ìjoba Orílẹ-èdè Nàìjíríà ti yan ìgbìmọ̀ ti yóò mú ìmọ̀isẹ́  dagba sì ni àgbáyé 

Àwọn ìgbimọ̀ ti yóò gbé làruge fún ìdàgbàsókè àti mìmọ́ fún aráyé láàrin àwọn ọ̀dọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Mínísítà fún ẹ̀tò ẹ̀kọ́, Dókítà Maruff Alausa ló Yan àwọn ìgbìmọ̀ yìí ni ìlu Abuja, O ni pàtàkì isẹ àwọn ìgbìmọ̀ náà ni ki wọn ri wí pè ìbáṣepọ̀ to dan mórán wa láàrin Orílè-èdè Nàìjíría àti àwọn Orílẹ̀-èdè toku lágbayé ki àwọn ènìyàn bá Le fi isẹ ọ̀wọ́ wọn hàn.

Dókítà Alausa ṣàlàyé wí pè igbesẹ yìí yóò mú ìdàgbàsókè ati irepo nla bá àgbáyé lápapọ̀.

Mínísítà ni láti nínú osù kẹjọ ọdun 2014 ni ìgbìyànjú ti n wa láti rí wí pè isẹ́ ọwọ́ gbórò, O ni ṣugbọn ọdun 2013 ni Orílè-èdè Nàìjíría ti n ni ìbáṣepọ̀ ati atilẹyin nla fún ètò náà

Comments are closed.

button