Take a fresh look at your lifestyle.

Akọ́ni-mọ̀ọ́gbá Liverpool Dunnú Láti Ki Salah Káàbọ̀ Padà Sínú Ikọ̀

139

Akoni-moogbá Liverpool, Arne Slot sọ pé inú òun n dun láti kí
agbábọ́ọ̀lù Mohamed Salah bọ̀ pada sinu ikọ̀ láti ibì idije Africa Cup of Nations (AFCON) lẹyin ọsẹ diẹ sẹyìn ti ko le bá àwọn akẹgbẹ rẹ kópa.

Agbábọ́ọ̀lù ọmọ ọdún mẹtalelọgbọn náà yóò wà pẹlu àwọn akẹgbẹ rẹ nigba ti wọn bá ń wakò pẹlu ikọ̀ Nàìjíríà ninu idije AFCON láti mọ ẹni ti yóò ṣe ipo kẹta ní òní ọjó Àbámẹ́ta. Osù kọkànlá ọdún to lọ ló ti kopa láti ibẹrẹ pẹlu ikọ̀ Liverpool gbeẹ̀yìn.

“Inu mi dùn pé o n padà bọ, bí mo tilẹ ní ògbóntàrigi agbábọ́ọ̀lù mẹẹdogun ní ayé rẹ, inu mi yóò sì tun dun láti kí káàbòlọ̀ sarin wa”, akoni-moogba,  Arne Slot sọ èyí.

Akọ́ni-moogbá náà sọ pé, bí wọn kò ṣè lu wà rárá ninu idije mọkanla ran wá lọwọ ní saa yìí.
Ọ̀mìn márùn ún ti a ni ti jẹ ká wà ni ipò karùn ún  lẹyìn ikọ̀ Arsenal to wà loke tente Tabili Premier Liìgì, ayò merinla lẹyìn Arsenal.

“A kò fi ara wa si ipò tó dára latàri ibi ti a wà lẹyìn ìdíje mẹ́fà,” o sọ èyí.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button