Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Gombe Bá Àwọn Àrinrìn-àjò Hajj Ẹgbẹ̀rún dín-ní-ogójì-dín-méjì Yọ̀

Lekan Orenuga

123

Gómìnà Muhammadu Yahaya tí Ìpínlẹ̀ Gombe tí fí ọrọ ránṣẹ́ sí àwọn àrinrìn-àjò ẹgbẹ̀rún-dín-ní-ogójì-dín-méjì (962) tí wọ́n fẹ́ ẹ ṣé Ìrìn-àjò sí Makkah fún Hajj l’ọdún 2025, Saudi Arabia.

‎ Nígbàtí o n sọrọ níbí ayẹyẹ idagbere náà ní Gombe, Gómìnà Yahaya ṣé ìdúpẹ́ nlá sí Ọlọhun Olódùmarè fún fífún àwọn àrinrìn-àjò náà ní àyè láti mú ọ̀kan nínú àwọn orígun ‘Islam’ márùn ṣẹ́.

‎ Gómìnà náà, tí Akọ̀wé Ìjọba ìpínlẹ̀ Gombe jẹ́ aṣojú fún Ibrahim Abubakar, ṣé àfihàn pàtàkì tí Ìrìn-àjò náà gẹ́gẹ́bí iṣẹ́ ìjọsìn tó béèrè fún ìṣaro ìjìnlẹ̀ àti isọdọtun tí ẹmí. 

Comments are closed.

button