Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kéde Ìbẹ̀rẹ̀ Àjọ̀dún Eré Ìdárayá Orílẹ̀-èdè

Lekan Orenuga

169

Tí ìdùnnú tí ayọ̀ ní gbogbo àwọn ènìyàn wà nílùú Abeokuta, tó jẹ́ olu-ilu ìpínlẹ̀ Ogun, nígbà tí Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ṣe kéde ayẹyẹ eré ìdárayá ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógún ní ìforígbárí, pẹ̀lú àwọn olóyè, àwọn olóṣèlú, àwọn ògbóǹtagí eré ìdárayá àtàwọn míì tí wọ́n ti rí ayẹyẹ náà.



‎ Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bola Tinubu tí igbákejì Ààrẹ, Kashim Shettima, ṣójú fún níbí ayẹyẹ eré ìdárayá.


‎ Ìdíje náà tí wọ́n fí ìsàmì rẹ̀ sọọ ‘Gateway 2024’, ní èrò láti ṣé agbega iṣọkan, dídára jùlọ ati ìwúrí orílẹ-èdè nípasẹ àwọn eré ìdárayá àti bí àwọn èèyàn jankan jankan tí tú jáde láti wà níbí ayẹyẹ naa.

Comments are closed.

button