Take a fresh look at your lifestyle.

Taiwo Awoniyi Àgbábọ́ọ̀lù Ọmọ Nàìjíríà Jí Pàdà Lẹ́yìn Iṣẹ́ Abẹ́ ‎

Lekan Orenuga

155

Àgbábọ́ọ̀lù ‘Super Eagles’ tí Nàìjíríà àti Nottingham Forest tí Orílẹ̀-èdè England, Taiwo Awoniyi, tí jí pàdà lẹ́yìn tó tí ṣiṣẹ́ abẹ́ lẹ́yìn ìpalára ikùn nlá kán tó ní lórí pápá.

‎ Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà fí ikùn kọlù ìgi golí ní iṣẹ́jú mejidinlaadọrun (88th minutes) níbí ifẹsẹwọnsẹ wọ́n nínú ìdíje ‘English Premier League’ tó yọrí sí amí ayo méjì-méjì (2-2) ní ọjọ́ Àìkú pẹ̀lú Leicester City. 

‎Taiwo tó pàdà sórí pápá lẹ́yìn àyẹwò àti ìtọ́jú, sùgbọ́n rọjú fún iṣẹ́jú mẹwàá tó kẹyin èrè náà.

‎ ‘Forest’, sọ ní ọjọ́ Ìṣẹgun pé Awoniyi tí ń bọsipọ dáradára lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ, sùgbọ́n wọ́n kó tíí dáhùn sí àwọn ìbéèrè kán.

Comments are closed.

button