Gíwá Àgbal Àjọ NILDS, Abubakar Ọlanrewaju Sulaiman ti pàrọwà sí àwọn òsìṣẹ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti tẹ̀síwájú nínú ojúse wọn kí wọ́n sì mú iṣẹ́ wọn ní òkúkúdùn
Sulaiman pàrọwà náà ní ỌJọ́bọ̀ níbi àyájọ́ òsìṣẹ́ tí ó wáyé ní ọjọ́ kíní osù karùn-ún níbi ọ̀rọ̀ ìkíni kú oríire tí ó wáyé láti ẹnu olùfọ̀rọ̀léde sí Gíwá Àgbà náà, Mohammed Abdulkadir níbí ayẹyẹ àyájọ́ òsìṣẹ́ ti ọdún 2025
Ó rán àwọn òsìṣẹ́ létí pàtàkì àyájọ́ náà, àtipé kí wọ́n máse kùnà nínú ojúse wọn fún ìtẹ̀síwájú Orílẹ̀-èdè