Take a fresh look at your lifestyle.

Àyájọ́ Òsìṣẹ́ : Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara Jẹ́jẹ̀ẹ́ Láti Pèsè Isẹ́ Èyí Tí Yóò Dẹ́kun Ài-̀ríṣẹ́se

62

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara, Abdulrahaman Abdulrasaq ti jẹ́jẹ̀ẹ́ ní Ọjọ́rú láti gbé  ìgbésẹ̀ èyí tí yóò mú kí ọjọ́ iwájú dára níbi tí isẹ́ yóò wà lọ́pọ̀ yanturu tí ara yóò sì dẹ tolórí-tẹlẹ́mù

 

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní àyájọ́ Òsìṣẹ́, Abdulrasaq gbósùbà fún àwọn òsìṣẹ́ jákè-jádò Ìpínlẹ̀ Kwara látàrí ìfarajì wọn, ó sàpèjúwe wọn gẹ́gẹ́ bí ọ̀pákùtẹ̀lẹ̀ fún ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú Orílẹ̀-èdè

 

Ó fí àrídájú hàn pé ìsèjọba rẹ̀ yóò tẹ̀síwájú nínú ojúse rẹ̀ láti fún àwọn òsìṣẹ́ lágbára, pèsè iṣẹ́, gbòòrò ìdókòòwò àti láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ọrọ̀ ajé lápapọ̀

 

 

 

Comments are closed.

button