Take a fresh look at your lifestyle.

Àyájọ́ Òsìṣẹ́ : Igbákejì Adarí Ilé Asòfin Kí Àwọn Òsìṣẹ́ Kú Oríire

60

Igbákejì Adarí Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin, Ọ̀gbẹ́ni Benjamin Kalu ti lu àwọn òsìṣẹ́ lọ́gọ ẹnu látàrí ipa tí wọn kó fún ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

 

Nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní àyájọ́ Òsìsẹ́ tí àgbáyé, ti ọdún 2025, Kalu sàfihàn ìpinnu ìsèjọba Ààrẹ Bọla Tinubu láti mú ìgbéga bá àwọn òsìṣẹ́, papàá jùlọ bíbuwọ́lu àlékún owó òsìṣẹ́ tí ó kéré jùlọ

 

Ó pàrọwà sí ọmọ Naijiria láti ní ìfaradà, kí wọ́n sì se àtìlẹyìn fún ìsejọba Ààrẹ Tinubu, ó wá fi àrídájú hàn pé àtúntò tí ó ń lọ lọ́wọ́ yóò so èso rere fún Orílẹ̀-èdè

 

Comments are closed.

button