Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Ààrẹ Shettima Kópa níbi Ayẹyẹ Òmìnira Ní Orílẹ̀-èdè Senegal

73

Igbákejì Ààrẹ, Kashim Shettima ti gbéra kúrò ní ìlú Abuja lọ sí Dakar, Senegal Láti sojú Ààrẹ Tinubu níbi ayẹyẹ òmìnira ọdúnkarùnlélọ́gọ́ta

 

Orílẹ̀-èdè Sengal ń se ayẹyẹ òmìnira ọlọ́dọọdún ní ọjọ́ kẹrin osù kẹrin, láti se ìrántí gbígba òmìnira kúrọ̀ lọ́wọ ìjọba amúnisìn Farase ní ọdún 1960

 

Lára àwọn ìlànà ètò náà ní ayẹyẹ, yíyan bí ológun, ohun ìsẹ̀ǹbáyé èyí tí o safihan pataki Orilẹ-ede

 

Ìrètí wà pé igbákejì Ààrẹ yóò padà sí Orílẹ̀-èdè Naijiria ní ọjọ́ Ẹtì, lẹ́yìn ayẹyẹ ọlọ́jọ́kan tí yóò wáyé ní gbọ̀ngàn Ọ́ọ́fìsì ààrẹ, ní ìlú Dakar

 

Comments are closed.

button