Take a fresh look at your lifestyle.

Isreal, Palestine Ṣé Pàṣípààrọ̀ Àwọn Òkú Àti Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n L’ójúnà Látí Fopin Sí Ogún

Lekan Orenuga

198

Isreal àti Palestine tí ṣé pàṣípààrọ̀ àwọn àpótí Òkú mẹ́rin kán tó jẹ́ tí àwọn ọmọ Israel tó kú sínú túbú, bí àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Palẹ́síténì tí wọ́n tí mọ́ ẹ̀wọ̀n àti àwọn tó wá ní atimọle tí gbá itu sílẹ ní Gaza àti àwọn tí ‘West Bank’ ní wọ́n ṣé pàṣípààrọ̀ wọ́n gẹ́gẹ́ bí àdéhùn apakan láti fopin sí ogún náà.

‎ Ìgbésẹ̀ náà jẹ́ àmì ìbẹrẹ tí pàṣípààrọ̀ nínú ogójì-ọjọ́-ati-méjì tí ìsinmi ogún láàrin Israeli atí Hamas, èyítí yóò parí ní ọ̀sẹ̀ yìí ayafi tí àdéhùn láti faagun bá tún wáyé. Ànfààní ìjíròrò wà fún ẹgbẹ́ méjèèjì láti fopin sí ogún náà ní ìbẹ̀rẹ̀ Oṣù yìí, ṣùgbọ́n kó sí àpẹẹrẹ pé ìjíròrò náà tí bẹ̀rẹ̀.

‎ Ẹká ológun tí Hamas, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Qassam, sọ ní Ọjọ́rú pé àwọn tó kú satimọle bí Tsachi Idan, Itzhak Elgarat, Ohad Yahalomi àti Shlomo Mantzur ní wọ́n tí fí ṣọwọ.

Comments are closed.

button