Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ Akin Niyín, Ẹ Kò Gbọdọ̀ Sojo- Ọ̀gágun Lagbaja Pàrọwà Sí Àwọn Ọmọ Ogun

60

Alákòsóo Àjọ Ọmọ Ogun (COAS) Ọ̀gágun Taoreed Lagbaja ti pàrọwà sí àwọn ọmọ ogun láti máse kùnà nínú ojúse wọn, kí wọ́n sì siṣẹ́ dójú àmì

 

Ó sọ ọ̀rọ̀ náà níbi àsekágbá àpérò ìpín alákọ̀kọ́ọ́ ti ọdún 2024 èyí tí ó wáyé ní ọ́ọ́fìsì àpapọ̀ àjọ ọmọ ogun tí ó wà ní ìlú Abuja

 

Ọ̀gágun Lagbaja gbóríyìn fún àwọn ọmọ ológun Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, papàá jùlọ àwọn adarí fún ojúse tí ó péye lásìkò tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ń kojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsòro

 

Comments are closed.