Ilé-iṣẹ́ ọmọ-ogún Nàìjíríà tí fèsì sí ìròyìn kàn látí ọ̀dọ̀ ‘Sahara Reporters, tí wọ́n fẹsùn kàn pé àwọn ọmọ-ogún tí wọ́n rán lọ́ sí Ìpínlẹ̀ Zamfara kó fún ní oúnjẹ dáradára àtí pé wọ́n kó tí sàn owó ajẹmọnu wọ́n ní Oṣù Kejìlá ọdún 2023.
Gẹ́gẹ́ bí ọrọ̀ kàn tí adele Ìgbákejì Alákóso, Ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn aráàlú, Lieutenant Colonel Ikechukwu Eze, Àdarí Gbogbogbò (GOC) ‘8 Division,’ Major General Godwin Mutkut, ní ìgbàgbogbo ní àwọn ń ṣàfihàn bí iṣẹ́ náà ṣé nlọ́ lọ́wọ́ ní Zamfara láti ríi dájú pé ètò ọrọ̀-ajé ìpínlẹ̀ náà ń tẹ̀síwájú.
Ó sọ pé fún ọsẹ méjì sẹyìn ní GOC tí ń jẹun látí inú ikòkò kànnà pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogún tó wà lábẹ́ rẹ̀, èyítí o ṣé àfihàn iṣẹ́ rẹ̀.