A tí rọ́ àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àgùnbánirọ̀ ní láti ṣé ìforúkọsílẹ pẹ̀lú Àwọn nọ́mbà Ìdánimọ̀ Orílẹ̀-èdè wọ́n (NIN) bẹ̀rẹ̀ látí 2024.
Èyí wà nínú àlàyé tí Olùdarí, ìròyìn àtí ibanisọrọ aráàlú tí Àjọ NYSC Ọ̀gbẹ́ni Eddy Megwa.
Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀gbẹ́ni Megwa tí sọ́, itọsọna náà jáde nínú ìpàdé àwọn alákóso tí NYSC tí Olùdarí Gbogbogbò, Brigadier General Yushau’ Ahmed dárí pẹ̀lú àwọn alákóso tí ‘National Identification Management Commission NIMC, tí Olùdarí gbogbogbò rẹ, Abisoye Coker-Odusote ní Abuja, Olú-ìlú Nàìjíríà