Olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (HoSF), Dókítà Folasade Yemi-Esan, tí gbá àwọn Akọ̀wé àgbà túntún níyànjú látí pá ọkàn wọ́n pọ̀ ṣiṣẹ́ tọ́ èròngbà ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu.
Ó sọ́ èyí làkókò tó ń ṣí dé ìpàdé ọlọọjọ́ méjì, ní Abuja. Ó fí yé wọ́n pé kí wọ́n ṣé abojuto sí àwọn iṣẹ́ wọ́n ní ìbámu sí ètò ìṣàkóso Ààrẹ Tinubu.
Yemi-Essan tún gbá àwọn Akọ̀wé túntún náà láwòrán láti máṣe já àwọn olórí òṣèlú tó fún wọ́n ní ànfààní náà kulẹ̀, àtí Ilé-iṣẹ́ náà.