Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbásepọ̀ Tí Ó Gbépọn Wáyé Láàrin Orílẹ̀-èdè Burkina Faso Àti Russia Lórí Ètò Ogun

0 181

Mínísítà Fún Ètò Àbò ti Orílẹ̀-èdè Burkina Faso, Kassoum Coulibaly ti gúnlẹ̀ sí Moscow

 

Ó sèpàdé pẹ̀lú Mínísítà Ètò Àbò Orílẹ̀-èdè Russia, wọ́n sì ní ìfẹnukò ìbásepọ̀ tí ó dán mọ́nrán

 

Burkinabe Kassoum Coulibaly sàpèjúwe ìgbésẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí èyí tí yóò so èso rere fún àwọn Orílẹ̀-èdè méjéèjì náà.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button