Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Sisi Kilọ Lòdì Sí ikọja Ààlà Nínú Rògbòdìyàn Tí Gaza

0 276

Ààrẹ Egypt Abdel Fattah al-Sisi ní ọjọ́ Àbámẹ́ta kìlọ sí èyíkéyìí òní kọjá ààlà nibi tí rògbòdìyàn Gaza, O sọ pé ẹnikẹni kó gbọ́dọ̀ kọjá àṣẹ orílẹ̀-èdè rẹ̀, lẹyìn tí duronu kàn wọn inú Egypt ni ọjọ́ Ẹtì.

Israeli ní ọjọ́ Ẹtì sọ pé ẹbí Yemen ní pẹ̀lú àtìlẹ́yìn Iran. Awọn ológun tí Egipti sọ pé àwọn duronu, tó já lúlẹ̀ nínú ìlú Egipti tí Taba àti Nuweiba nítòsí Ààlà Israeli, tó ṣé ìpalára fún ènìyàn mẹ́fà, ṣùgbọ́n wọ́n kó sọ ẹni tó ní duronu náà.

Sisi ṣé àpéjọ àlàfíà kàn ní ọjọ́ Àbámẹ́ta tó kọjá láti ṣé ìrànlọ́wọ́ ìgbà láàyè sí Gasa, kí wọ́n tú àwọn tí wọ́n mú sílẹ̀, àtí láti wá òpin sí ogún Israeli-Hamas.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button