Take a fresh look at your lifestyle.

Jẹjẹrẹ Ọkàn: Àjọ Aláànúú Ọmọnìyàn Kan Sanwó Iṣẹ́ Abẹ Ọmọ Ọdún Mẹ́tàlá

0 234

Àjọ aláànúú ọmọnìyàn kan ti nawọ́ ìrànlọ́wọ́ pẹ̀lú sísanwó iṣẹ́ abẹ àrùn jẹjẹrẹ ọkàn fún ọmọ ọdún mẹ́tàlá kan tí àrùn náà ń bá fínra.

 

Olùdásílè àjọ náà, Dókítà Mistura Lawal-Arowona ni ó síṣọ lójú ọ̀rọ̀ náà níbi ayẹyẹ àsekágbá ètò ìkẹ́ẹ̀kọ́ jáde rẹ̀ ní ìlú Ilọrin.

 

Ó tẹ̀síwájú pé Òun dá àjọ náà sílẹ̀ láti ara ìnífẹ̀ẹ́sí ìrànlọ́wọ́ ọmọnìyàn, ìpèsè ìtọ́jú àti àyẹ̀wò tí ó péye, àti fún ìgbáyégbádùn àwùjọ.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button