Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó tí fí dá àwọn aráàlú lójú pé ìyára àti ìṣàkóso àwọn ọran ìwà-ipá tó dá lórí ààbò ní Ìpínlẹ̀ náà.
Ìjọba nípasẹ Ilé-iṣẹ́ Ìwà-ipá abẹ́lé àti ìbálòpọ̀ ipá tí Ìpínlẹ̀ Èkó, DSVA fúnni ní ìdánilójú níbi ìfilọ́lẹ̀ Ìpàdé Àpéjọ ipẹjọ àti DSVCMS.
![]()
Nígbà tó nsọ̀rọ níbi ìfilọ́lẹ̀ ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àpéjọ náà, Akọ̀wé àgbà àti Aláṣẹ tí Ile-ibawi Ìwà-ipá abẹ́lé àti ìbálòpọ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó, DSVA, Arabinrin Titilola Vivour-Adeniyi ṣàlàyé pé ìgbésẹ náà ṣé dàndàn láti dẹkùn rògbòdìyàn òràn ìbálòpọ̀, ìwà-ipá tó dá lórí àbò àti ìṣàkóso pẹlu ọwọ.
Leave a Reply