Take a fresh look at your lifestyle.

Inú Àwon Ènìyàn Dùn Bí GolfSixes Ṣé Parí Sí Réré Ní Ilú Èkó

0 271

Ìyálóde tí Ìpínlẹ̀ Èkó, Bintu Tinubu àti Innocent Ike, Olùdarí àti Alákóso tí. bánkì Polaris tẹ́lẹ̀ rí, tí gbóríyìn fún àwọn tó ṣètò Golfsixses tó ṣẹṣẹ parí, ìdíje gọọfu fún àwọn àgbàlagbà.

Ọrọ̀ kàn tí Steve Oma-Ofozo, Alàkóso ìròyìn tí ìdíje náà, ní Ìlú Èkó, sọ pé àwọn méjèèjì sọ̀rọ̀ náà làkókò ìdíje Golfsixses 2023 èyí tó wáyé ní Ikeja Golf Club.

Tinubu sọ pé ìdíje náà, tó jẹ́ tí àwọn àgbàlagbà àti àwọn òṣìṣẹ́ fẹyìntì fún àwọn olukopa láti fí ará wọ́n hàn.

Ní èrò kànnà, Ike, tó ń kópa nígbà àkọ́kọ́, sọ pé ìyè àwọn àgbábọ́ọ̀lù gọọfu tí ọdún yìí 2023, fí pàtàkì ìdíje náà hàn pàápàá jùlọ láàrin àwọn àgbàlagbà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button