Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé-ẹjọ́ Indonesia Kọ̀ Láti Yí Òfin Láti Dì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Náà Pàdà

0 298

Ilé-ẹjọ́ Indonesia kàn ní ọjọ́ Ajé tí kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ipè láti yí àwọn òfin yíyan ní sípò Ààrẹ àti ìgbákejì Ààrẹ pàdà.

Ilé-ẹjọ́ tí ṣé àwọn ìdájọ lórí àwọn ipè tó jọra ní ọjọ́ Ajé, àwọn alatako sọ pé ìgbésẹ Ààrẹ Joko Widodo láti ṣé idasilẹ ẹgbẹ́ Òṣèlú tí yóò lágbára lẹyìn àkókò tí gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.

Ètò ìdìbò Ààrẹ àti àwọn aṣòfin Orílẹ̀-èdè náà yóò wáyé ní ọjọ́ kẹrinla, oṣù Kejì ọdún tó ń bọ̀.

Adájọ àgbà Anwar Usman àti àwọn akẹgbẹ rẹ̀, kọ́ àwọn àbá láti ṣé adínkù ọjọ́-orí tó kéré jù sí ọdún mẹ̀édọ́gbọn (35years) látí ogójì ọdún (40 years) àti láti gbá ẹnikẹni tó ní ìrírí nípa iṣẹ́ ìlú láàyè láti dije fún Ààrẹ àti Ìgbákejì Ààrẹ.

Àwọn onídájọ́ náà sọ pé ìpinnu àti ṣé ìyípadà iye ọjọ-ori wà lọ́wọ́ àwọn aṣòfin àti pé àbá náà kò ní “ìdí ní ìbámu sí òfin

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button