Take a fresh look at your lifestyle.

Abuja: Àjọ Tó Ń Gbógun Tí Òògùn Olóró Gbá Èyí Tó Tó Ọgọrín Mílíọ̀nù Náírà

0 285

Àjọ tó gbógun tí oògùn olóró tí Orílẹ̀-èdè (NDLEA) ẹ̀ka tí Abuja tí gbá òògùn olóró tó dín díẹ̀ ní ẹgbẹ̀rún mẹ́rin kilo (3,988.74 kilogrammes) èyí tó jẹ́ ọgọrin mílíọ̀nù Náírà.

Adari àti alàkóso Àjọ náà ní Abuja, Ọ̀gbẹ́ni Kabir Tsakuwa sọ èyí ní ifọrọwanilẹnuwo pẹ̀lú àwọn oníròyìn ní Ọjọ́ Àjé ní Abuja, Olú-ìlú orílẹ̀-èdè náà.

Tsakuwa sọ pé ó lè ní aadoje (134) àwọn ẹní á fúnra sí tí ọwọ tí bá.

Àwọn oògùn olóró oríṣiríṣi bíi igbó (cannabis Sativa), Cocaine, Methamphetamine, Tramadol, Rohypnol àti Diazepam

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button