Gómìnà Muhammadu Inuwa ti ìpínlẹ̀ Gombe ti se ìfiléde ìpinnu rẹ̀ láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ẹ̀kọ́ àti ìgbáyégbádùn àwọn olúkọ́.
Ó tún gbèrò láti pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn láti mú ìrọ̀rùn bá iṣẹ́ síṣe ní ẹka ètò ẹ̀kọ́
Gómìnà sọ ọ̀rọ̀ náà níbi àyájọ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí ó wáyé jákè-jádò gbogbo àgbáyé.
Leave a Reply