Lionel Messi gbá bọ́ọ̀lù àgbàyànú wọ́ awọ̀n bí ó ṣé gbá ìfé ẹ̀yẹ àkọ́kọ́ rẹ̀ ní Àríwá America bí Inter Miami ṣé ná Nashville ní àbálá ẹní bá láyà (10-9) lẹyìn tí Ifẹsẹwọnsẹ wọ́n ṣé parí ní ọ̀mì 1-1 ní iṣẹju àádọ́rún.
Messi ló kọ́kọ́ gbábọ̀ọ́lù sàwọ̀n ní iṣẹ́jú mérin-lè-lógún ṣùgbọ́n Fafa Picault dá pàdà nì ìpele Kejì fún Nashville.
Ní ìkẹyìn, wọ́n wọ́ àbala ẹní-bá-láyà níbí tí goli ìkọ méjèèjì tí kojú síra wọ́n èyítí Elliot Panicco pàdánù sọwọ́ goli Miami, Drake Callender.
Leave a Reply