Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Se Àyájọ́ Ìfọ́mọlọ́yàn Dé Ògóńgó Pẹ̀lú Àwọn Akẹgbẹ́ Rẹ̀ Ní Àgbáyé

0 208

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà darapọ̀ mọ́ akẹgbẹ́ rẹ̀ lágbàyéé láti se àyájọ́ fífún ọmọ lọ́yàn, ìjọba sọ pé àìfún ọmọ lọ́yàn gẹ́gẹ́ bí ó se yẹ jẹ́ nǹkan tí ó n kọni lóminú.

 

Ìjọba tẹ̀síwájú pé ó se pàtàkì láti fún ọmọ lọyan ni kété ti wọn bá ti bí ọmọ naa àtipé wọn gbọdọ fun ọmọ na ni ọyan nìkan fun osù mẹ́fà àkọ́kọ́, ti yoo si tẹ siwaju ti ọmọ naa yoo fi pe ọdun meji pẹlu awọn ounjẹ ti o yẹ lẹyin osu mẹfa.

 

Ijọba sàfirinlẹ̀ pé, àyè gbọdọ wa fun awọn osiṣẹ ti o n fun ọmọ lọyan lati se bẹ́ẹ̀, nitori pe yoo fun awọn obinrin laye lati tẹsiwaju ninu iṣẹ wọn lasiko titọ ọmọ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button