Take a fresh look at your lifestyle.

Lórí Ẹjọ́ Tí Atiku Pè Tako Ìjáwé Olúboŕi Ààrẹ Tinubu, Ilé Ẹjọ́ Sún Ìdájọ́ síwájú

0 197

Ilé Ẹjọ́ tí ó ń gbọ́ ìfẹ̀hónúhàn lórí ìdìbò gbogbogbòò tí ó kọjá ti sún ìdájọ́ síwájú lórí ẹjọ́ tí olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP, Atiku Abubakar pè tako ìjáwé olúborí Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu.

 

Adájọ́ Haruna Tsamani ni o fi ọrọ lede, lẹ́yìn ìgbà tí Atiku parí fífi ìdí àwọn ẹ̀rí rẹ̀ múlẹ̀ fún ilé ẹjọ́.

 

Igbákejì ààrẹ tẹ́lẹ̀rí àti ẹgbẹ́ PDP tako àbájáde ìbò pẹ̀lú ẹ̀sùn wípé màgò-mágó wáyé nínú èsì ìdìbò náà. Wọ́n wá pàrọwà sí ilé ẹjọ́ láti fagilé èsì ìbò náà, kí àtúndì ìbò míràn sì wáyé.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button