Take a fresh look at your lifestyle.

Ìbásepọ̀ Yóò Wáyé Láàrin Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Bangladesh Lójúnà Àti Mú Ìgbòòrò Bá Ètò Ọ̀gbìn

0 178

Ìjọba Àpapọ̀ ti fi ìgbáradì rẹ̀ léde láti fi ọwọ́ sowọ́pọ̀ pẹ̀lú Bangladesh lórí ètò ọ̀gbìn ìgbàlódé lójúnà àti mú ìgbòòrò bá ètò ọ̀gbìn àti ìbásepọ̀ tí ó múná dóko láàrin Orílẹ̀-èdè méjéèjì náà.

 

Arábìnrin Anthonia Eremah ti ẹka ètò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè ìgbèríko fún ìjọba àpapọ̀ ni ó fi ọ̀rọ̀ náà léde ni ọjọ́ Ajé , ní ìlú Abuja.

 

Ó fi àrídájú hàn pé, ìbásepọ̀ náà yóò mú kí oúnjẹ pọ̀ yanturu, ìpèsè iṣẹ́, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button