Take a fresh look at your lifestyle.

Tobi Amusan Tún Fakọyo Nínú ìdíje Tó Ń Lọ Lọ́wọ́ Ní Orílẹ̀-èdè Jamaica.

0 230

Ìlú mọ̀ọ́ká àgbáyé ni Tóbi Amusan tún ti jáwé bóri nínú ìdíje to ńlọ le ní Orílẹ̀-èdè Jamaica.

Amusan to ti kókó fẹ̀yìn le lẹ nínú ìdíje náà tẹ́lẹ̀ rí ,pẹ̀lú Puerto Rico Jasmine Camacho -Quinn tó jáwé bóri ni àkókò naa .

Ṣùgbọ́n ni àkókò yìi ọmọ ọdún mẹ́rìndiínlọ́gbọ̀n náà jáwé Olubori oluga 12.57.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button