Akọ̀wé Ìpínlẹ̀ Amẹ́ríkà nígbàkan rí, Hillary Clinton kéde ní ọjọ́ ajé, pé òhun ti kó ààrùn COVID-19 pẹ̀lú àmì àìsàn wérẹ́.
Eni ti o jẹ Ọmọ ọdun mẹrinle-laadọrin naa, ti o tun jẹ ẹni ti ẹgbẹ Democratic yan fun ipo aarẹ fun ibo ọdun 2016, sọ pe, ohun ti gba abẹrẹ ajesara bẹẹni ohun si ti n gbadun.
Ọkọ rẹ, Aarẹ orilẹ-ede Amẹrika nigbakan ri Bill Clinton, ṣe ayẹwo aarun ọhun ti o si jege ni ọjọ iṣẹgun ti o si ti n gbadun.
Leave a Reply