Àjò ò lè dà bí ilé
Àjọ tó ń rísí ètò pàjáwìrì ní orílẹ̀-èdè, (NEMA) ní ọjọ́ọ́rú, gba àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà márùndín-lọ́gọ́rùn ún (95) tí wọ́n ti tàn sí orílẹ̀-èdè Líbíyà, ní pápá ọkọ̀ òfurufú Múrítàlá…