Ile Aṣofin Eko Bẹrẹ Ayẹwo Iṣẹ Awọn Ijọba Ibilẹ
Apapọ Igbimọ to n moju to Apo Owo Ijọba Ibilẹ ati Igbimọ to n moju to Iṣakoso Ijọba Ibilẹ ati Agbegbe rẹ ninu Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko labẹ Oludari wọn, Aṣofin Mudashiru Ọbasa, bẹrẹ ṣiṣe ayẹwo iṣẹ awọn ogun…