Ilé Aṣòfin Èkó gbé òṣùbà o-káre ọmo ̣ọ̀dọ̀ rere fún Àar̀ẹ Tinubu fún…
Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko ki Aarẹ Bọla Ahmed Tinubu ti orilẹ-ede Naijiria ku oriire ọgọrun ọjọ lori aleefa, wọn gboriyin fun iṣẹ takuntakun rẹ.
Awọn ọmọ ẹgbẹ Ile Aṣofin Eko woye pe, akitiyan Aarẹ ko ṣaifara han…