Ilé Aṣòfin Èkó fọwọ́ sí àwọn orúkọ mẹ́ta tí ̣Gómìnà fi ṣọwọ́ sí wọn fún ipò…
Ile Igbimọ Aṣofin Ipinlẹ Eko labẹ Oludari Ile Aṣofin naa Aṣofin Mudashiru Ọbasa, ti fọwọ si awọn orukọ ti ̣Gomina Babajide Sanwo-Olu fi ṣọwọ si Ile wọn gẹgẹ bi ara igbimọ alaṣẹ ẹka amuṣẹṣe ijọba Ipinlẹ Eko
Ile…