Take a fresh look at your lifestyle.

Ìṣe Àti Àṣà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Àti Benin jẹ́ Bákan náà- Ààrẹ Tinubu

0 174

Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Bọla Tinubu sọ wípé Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Benin jọ arawọn nípa Àṣà, Ìtàn àti ìṣe, àtipé ànfààní náà yóò mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè méjéèjì náà.

 

Ààrẹ Tinubu wòye ọ̀rọ̀ náà ní ìlu Cotonou, olú ìlú Benin nígbà tí ó lọ gẹ́gẹ́ bí àlejò pàtàkì níbi àyájọ́ òmìnira ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́ta tí Orílẹ̀-èdè Benin ń se.

 

Ó wòye ọ̀rọ̀ pé, sísúnmọ́ra àwọn Orílẹ̀-èdè méjéèjì, jíjọra nípa ètò ọrọ̀ ajé àti ìdàgbàsókè yóò mú ìbásepọ̀ àti ìrànlọ́wọ́ bá orílẹ̀-èdè méjéèjì náà.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button