Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Gómìnà Tẹ́lẹ̀rí Pèpè Àtìlẹyìn Fún Ààrẹ Tinubu

0 208

Àwọn Gómìnà tẹ́lẹ̀rí ti ọdún 1999 ti pàrọwà sí ọmọ Nàìjíríà láti se àtìlẹyìn fún Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu gẹ́gẹ́ bí ó se ń tukọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

 

Wọ́n pe ìpè náà nínú ìfọ̀rọ̀-wáni-lẹ́nu-wò pẹ̀lú àwọn oníròyìn nígbà tí wọn se abẹwo si Aarẹ Tinubu ni ilu Abuja.

 

Adarí ikọ̀ náà, Gómìnà ìpínlẹ Edo tẹ́lẹ̀rí, Lucky Igbinedion sọ pe, Aarẹ ni àfojúsùn rere fun Orilẹ-ede Naijiria.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button