Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ebonyi Fọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Àwọn Ọ̀dọ́ Fún Ìdàgbàsókè Àti Ìlọsíwájú Ìpínlẹ̀ Ebonyi
Adarí àwọn Ọ̀dọ́ tí ẹgbẹ́ APC ní ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀tàlá tí ó wà ní ìpínlẹ̀ náà ni ó ti ní àjọsepọ̀ pẹ̀lú olùrànlọ́wọ́ pàtàkì sí gómìnà lórí ìdàgbàsókè àwọn ọ̀dọ́, Ọ̀gbẹ́ni Eze Paul láti jẹ́ kí ìpínlẹ̀ Ebonyi jẹ́ ibùgbé ìrọ̀rùn fún mùtú-mùwà.
Àwọn ọ̀dọ́ náà gbèrò ìbásepọ̀ lórí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ ọwọ́ fún àwọn akẹgbẹ́ wọn ni ipinlẹ naa.
Alaga awọn ọdọ naa, Ọgbẹni Nwancho Uchenna parọwa si ijọba fun ikopa awọn ọdọ ninu ètò ijọba gbogbo.
Leave a Reply