Ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu ti ráńsẹ́ ìbánikẹ́dùn sí ẹka ìdájọ́ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà látàrí ìpapòdà Adájọ́ Chima Nweze àti Peter Mallong tí wọ́n jẹ́ ògúnná gbòǹgbò ní ẹka ìdájọ́
Adájọ́ ilé ẹjọ́ gíga àpapọ̀ ẹni tí ó pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ ni ẹni ọdún mẹ́rìnlélọ́gọ́ta ni ààrẹ tẹ́lẹ̀rí Goodluck Jonathan yan sipo ni ọdun 2014.
Aarẹ Tinubu wa kẹ́dùn pẹ̀lú adajọ agba ilẹ Naijiria, Olukayọde Ariwoọla ati Adajọ ile ẹjọ giga, Husseini baba-Yusuf lori iku akẹgbẹ wọn
Leave a Reply