Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Di Ọmọ Ọgọ́ta Ọdún- Gómìnà Dáwọ̀ọ́ Ìdùnnú pẹ̀lú Rẹ̀

0 197

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara AbdulRahaman AbdulRasaq ti kí igbákejì rẹ̀, Ọ̀gbẹ́ni Kayọde Alabi kú oríire fún ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdún, ó gbàdúrà ìgbé ayé rere, àti àlàáfíà fún-un.

 

Gómìnà sàpèjúwe ọlọ́jọ́ ìbí náà gẹ́gẹ́ bí olóòtọ́ọ́, aláànúú ènìyàn, ó wá dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀ fún ìfarajì àti ipa ribiribi rẹ̀ fún àseyọrí ìsèjọba wọn láti ọdún 2019.

 

Gómìnà gbàdúrà kí ọlọ́run jẹ́ kí Kayọde Alabi se ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún láyé.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button