Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno Bẹ̀rẹ̀ Pínpín Àwọn Ohun Amáyédẹrùn Látàrí Yíyọ Ìrànwọ́ Orí Epo

0 174

Gómìnà ìpínlẹ̀ Borno, Babagana Zulum ti bẹ̀rẹ̀ láti máa pín àwọn ohun amáyédẹrùn fún àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà láti sọ ìlekoko tí yíyọ ìrànwọ́ orí epo dá sílẹ̀ di ìrọ̀rùn.

 

Gomina Zulum ba àwọn akọ̀ròyìn sọ̀rọ̀ ní Muna, nibi ti eto naa ti waye, Ó ní pinpin oúnjẹ ati awọn ohun amáyédẹrùn míràn fún àwọn tí ìdágìrì lé kúrò ní àgbègbè wọn jẹ́ ọ̀nà tí ìjọba le gbà ràn wọ́n lọ́wọ́ àti láti mú ìrọ̀rùn bá ìgbé ayé wọn.

 

Ó tẹ̀síwájú pe ẹgbẹrun mẹjọ le lọọdunrun awọn obinrin ni yoo jẹ ànfààní gbígba ẹgbẹ̀rún márùn-ún naira ati asọ, nigba ti awọn baale ẹgbẹrun marun-un yoo gba apo irẹsi ati ẹwa.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button